Wọlé sí Áfríkà titun! Káàbọ̀ sí Ilé-àkójọpọ̀ Ouidah ní Benin!

Ilé-iṣẹ́ Zinsou pẹ̀lú ìrànlọwọ́ Christian Langlois-Meurinne àti IDI bẹ̀rẹ̀ ètò àìrídìmú WAKPON – Ilé-àkójọpọ̀ l'òde.


Ní gbogbo àgbáyé, ètò àìrídìmúWAKPON n jẹ kí àwọn aṣàmúlò rẹ ṣe ìwárí àwọn oníṣẹ́-ọnà àtọwọdá mẹ̀wá tí o jẹ ara àwọn iṣẹ́ àwòràn Ilé-ìpamọ ọlọ́jọ́pípẹ́ Ouidah, gẹgẹbi ìrírí titun.

Labójútó Ọgbẹni Pierrick Chabi, ètò àìrídìmú yí tí o ṣe didálẹ n lò àfídamọ tẹknọ́lọ́jì tí a n pe ní "àfojúinú ṣe ohun rírí".

Dá ilé-àkójọpọ rẹ ní ìgbésẹ́ márùn!

1 -e gbígbà fáìlì àwọn Ẹ̀dà Àwòrán Aládùn

2 - Lẹ̀ wọn sórí aṣàfihàn ohun-élò rẹ

3 - Ṣe gbígbà ètò àìrídìmú WAKPON

4 - Ṣi  lórí kọ̀mpútà tàbí fóònù alàgbéká rẹ

5 -Wò àwọn Ẹ̀dà Àwòrán Aládùn náà lórí ohun-élò rẹ

ArtYOR.html
Ṣe ìwádì àwọn iṣẹ́ àwòránArtYOR.html
Wakpon_Magic.html
Ṣe títẹ̀ àwọn Ẹ̀dà Àwòrán AládùnWakpon_Magic.html
Wakpon.html
WakponInfo.html
iWakponInfo.html

WAKPON – Ilé-àkójọpọ̀ l'òde jẹ ètò àìrídìmú Ilé-iṣẹ́Zinsou.